Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oni 7:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo si ri ohun ti o korò jù ikú lọ, ani obinrin ti aiya rẹ̀ iṣe idẹkun ati àwọn, ati ọwọ rẹ̀ bi ọbára: ẹnikẹni ti inu Ọlọrun dùn si yio bọ lọwọ rẹ̀; ṣugbọn ẹlẹṣẹ li a o ti ọwọ rẹ̀ mu.

Ka pipe ipin Oni 7

Wo Oni 7:26 ni o tọ