Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oni 3:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi mọ̀ pe ohunkohun ti Ọlọrun ṣe yio wà lailai: a kò le fi ohun kan kún u, bẹ̃li a kò le mu ohun kan kuro ninu rẹ̀; Ọlọrun si ṣe eyi ki enia ki o le ma bẹ̀ru rẹ̀.

Ka pipe ipin Oni 3

Wo Oni 3:14 ni o tọ