Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oni 2:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoripe Ọlọrun fun enia ti o tọ li oju rẹ̀ li ọgbọ́n, ati ìmọ ati ayọ̀: ṣugbọn ẹlẹṣẹ li o fi ìṣẹ́ fun, lati ma kó jọ ati lati ma tò jọ ki on ki o le ma fi fun ẹni rere niwaju Ọlọrun. Eyi pẹlu asan ni ati imulẹmofo.

Ka pipe ipin Oni 2

Wo Oni 2:26 ni o tọ