Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oni 12:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li ọjọ ti awọn oluṣọ ile yio warìri, ati ti awọn ọkunrin alagbara yio tẹri wọn ba, awọn õlọ̀ yio si dakẹ nitoriti nwọn kò to nkan, ati awọn ti nwode loju ferese yio ṣu òkunkun,

Ka pipe ipin Oni 12

Wo Oni 12:3 ni o tọ