Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oni 11:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ni kutukutu fún irugbin rẹ, ati li aṣãlẹ máṣe da ọwọ rẹ duro: nitori ti iwọ kò mọ̀ eyi ti yio ṣe rere, yala eyi tabi eyini, tabi bi awọn mejeji yio dara bakanna.

Ka pipe ipin Oni 11

Wo Oni 11:6 ni o tọ