Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oba 1:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn ẹni imulẹ rẹ ti mu ọ de opin ilẹ rẹ: awọn ti nwọn ti wà li alafia pẹlu rẹ ti tàn ọ jẹ, nwọn si bori rẹ; awọn ti o jẹ onjẹ rẹ ti fi ọgbẹ́ si abẹ rẹ: oye kò si ninu rẹ̀.

Ka pipe ipin Oba 1

Wo Oba 1:7 ni o tọ