Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oba 1:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi awọn olè tọ̀ ọ wá, bi awọn ọlọṣà li oru, (bawo li a ti ke ọ kuro!) nwọn kì yio ha jale titi nwọn fi ni to? bi awọn aka-eso-ajara wá sọdọ rẹ, nwọn kì yio ha fi ẽṣẹ́ diẹ silẹ?

Ka pipe ipin Oba 1

Wo Oba 1:5 ni o tọ