Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oba 1:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn iwọ kì ba ti ṣiju wo ọjọ arakunrin rẹ ni ọjọ ti on di ajeji; bẹ̃ni iwọ kì ba ti yọ̀ lori awọn ọmọ Juda ni ọjọ iparun wọn; bẹ̃ni iwọ kì ba ti sọ̀rọ irera ni ọjọ wahala.

Ka pipe ipin Oba 1

Wo Oba 1:12 ni o tọ