Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Sol 6:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọkan ni adaba mi, alailabawọn mi; on nikanṣoṣo ni ti iya rẹ̀, on ni ãyo ẹniti o bi i. Awọn ọmọbinrin ri i, nwọn si sure fun u; ani awọn ayaba ati awọn àle, nwọn si yìn i.

Ka pipe ipin O. Sol 6

Wo O. Sol 6:9 ni o tọ