Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Sol 4:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

WÒ o, iwọ li ẹwà, olufẹ mi: wò o, iwọ li ẹwà; iwọ li oju àdaba labẹ iboju rẹ: irun rẹ dabi ọwọ́ ewurẹ, ti o dubulẹ lori òke Gileadi.

Ka pipe ipin O. Sol 4

Wo O. Sol 4:1 ni o tọ