Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Sol 3:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi mo ti fi wọn silẹ gẹrẹ ni mo ri ẹniti ọkàn mi fẹ: mo dì i mu, emi kò si jọ̃rẹ̀ lọwọ, titi mo fi mu u wá sinu ile iya mi, ati sinu iyẹwu ẹniti o loyun mi.

Ka pipe ipin O. Sol 3

Wo O. Sol 3:4 ni o tọ