Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Sol 3:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ jade lọ, Ẹnyin ọmọbinrin Sioni, ki ẹ si wò Solomoni, ọba, ti on ti ade ti iya rẹ̀ fi de e li ọjọ igbeyawo rẹ̀, ati li ọjọ ayọ̀ ọkàn rẹ̀.

Ka pipe ipin O. Sol 3

Wo O. Sol 3:11 ni o tọ