Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 99:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. OLUWA jọba; jẹ ki awọn enia ki o wariri: o joko lori awọn kerubu; ki aiye ki o ta gbọ̀ngbọ́n.

2. Oluwa tobi ni Sioni: o si ga jù gbogbo orilẹ-ède lọ.

3. Ki nwọn ki o yìn orukọ rẹ ti o tobi, ti o si li ẹ̀ru; mimọ́ li on.

Ka pipe ipin O. Daf 99