Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 96:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. Ẹ kọrin titun si Oluwa: ẹ kọrin si Oluwa gbogbo aiye.

2. Ẹ kọrin si Oluwa, fi ibukún fun orukọ rẹ̀; ẹ ma fi igbala rẹ̀ hàn lati ọjọ de ọjọ.

3. Sọ̀rọ ogo rẹ̀ lãrin awọn keferi, ati iṣẹ iyanu rẹ̀ lãrin gbogbo enia.

Ka pipe ipin O. Daf 96