Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 95:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ jẹ ki a fi ọpẹ wá si iwaju rẹ̀, ki a si fi orin mimọ́ hó iho ayọ̀ si ọdọ rẹ̀.

Ka pipe ipin O. Daf 95

Wo O. Daf 95:2 ni o tọ