Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 84:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitõtọ, ologoṣẹ ri ile, ati alapandẹdẹ tẹ́ itẹ fun ara rẹ̀, nibiti yio gbe ma pa awọn ọmọ rẹ̀ mọ́ si, ani ni pẹpẹ rẹ wọnni, Oluwa awọn ọmọ-ogun, Ọba mi ati Ọlọrun mi.

Ka pipe ipin O. Daf 84

Wo O. Daf 84:3 ni o tọ