Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 79:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃li awa enia rẹ ati agutan papa rẹ, yio ma fi ọpẹ fun ọ lailai, awa o ma fi iyìn rẹ hàn lati irandiran.

Ka pipe ipin O. Daf 79

Wo O. Daf 79:13 ni o tọ