Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 67:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. KI Ọlọrun ki o ṣãnu fun wa, ki o si busi i fun wa; ki o si ṣe oju rẹ̀ ki o mọlẹ si wa lara,

2. Ki ọ̀na rẹ ki o le di mimọ̀ li aiye, ati igbala ilera rẹ ni gbogbo orilẹ-ède.

3. Jẹ ki awọn enia ki o yìn ọ, Ọlọrun; jẹ ki gbogbo enia ki o yìn ọ.

Ka pipe ipin O. Daf 67