Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 65:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Agbo ẹran li a fi wọ̀ pápá-tútù na li aṣọ: afonifoji li a fi ọka bò mọlẹ: nwọn nhó fun ayọ̀, nwọn nkọrin pẹlu.

Ka pipe ipin O. Daf 65

Wo O. Daf 65:13 ni o tọ