Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 63:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ọba yio ma yọ̀ ninu Ọlọrun; olukuluku ẹniti o nfi i bura ni yio ṣogo: ṣugbọn awọn ti nṣeke li a o pa li ẹnu mọ́.

Ka pipe ipin O. Daf 63

Wo O. Daf 63:11 ni o tọ