Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 62:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. ỌLỌRUN nikan li ọkàn mi duro jẹ dè; lati ọdọ rẹ̀ wá ni igbala mi.

2. On nikan li apata mi ati igbala mi; on li àbo mi, emi kì yio ṣipò pada jọjọ.

Ka pipe ipin O. Daf 62