Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 55:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti kì iṣe ọta li o gàn mi: njẹ emi iba pa a mọra: bẹ̃ni kì iṣe ẹniti o korira mi li o gbé ara rẹ̀ ga si mi; njẹ emi iba fi ara mi pamọ́ kuro lọdọ rẹ̀:

Ka pipe ipin O. Daf 55

Wo O. Daf 55:12 ni o tọ