Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 51:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ, iwọ nikanṣoṣo ni mo ṣẹ̀ si, ti mo ṣe buburu yi niwaju rẹ: ki a le da ọ lare, nigbati iwọ ba nsọ̀rọ, ki ara rẹ ki o le mọ́, nigbati iwọ ba nṣe idajọ.

Ka pipe ipin O. Daf 51

Wo O. Daf 51:4 ni o tọ