Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 5:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori iwọ, Oluwa, ni yio bukún fun olododo; oju-rere ni iwọ o fi yi i ka bi asà.

Ka pipe ipin O. Daf 5

Wo O. Daf 5:12 ni o tọ