Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 49:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. ẸGBỌ́ eyi, gbogbo enia; ẹ fi eti si i, gbogbo ẹnyin araiye:

2. Ati awọn ọmọ-ẹhin ati awọn ẹni-ọlá, awọn ọlọrọ̀ ati awọn talaka pẹlu.

3. Ẹnu mi yio sọ̀rọ ọgbọ́n, ati iṣaro aiya mi yio jẹ oye.

Ka pipe ipin O. Daf 49