Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 48:1-4 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. ẸNI-NLA ni Oluwa, ti ã yìn pupọpupọ, ni ilu Ọlọrun wa, li oke ìwa-mimọ́ rẹ̀.

2. Didara ni ipò itẹdo, ayọ̀ gbogbo aiye li òke Sioni, ni iha ariwa, ilu Ọba nla.

3. A mọ̀ Ọlọrun li àbo ninu ãfin rẹ̀.

4. Sa wò o, awọn ọba pejọ pọ̀, nwọn jumọ nkọja lọ.

Ka pipe ipin O. Daf 48