Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 47:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. ẸNYIN enia, gbogbo ẹ ṣapẹ; ẹ fi ohùn ayọ̀ hó ihó iṣẹgun si Ọlọrun.

2. Nitori Oluwa Ọga-ogo li ẹ̀ru; on li ọba nla lori ilẹ-aiye gbogbo.

3. On ni yio ṣẹ́ awọn enia labẹ wa, ati awọn orilẹ-ède li atẹlẹsẹ wa.

Ka pipe ipin O. Daf 47