Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 40:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki gbogbo awọn ti nwá ọ, ki o ma yọ̀, ki inu wọn ki o si ma dùn sipa tirẹ: ki gbogbo awọn ti o si fẹ igbala rẹ ki o ma wi nigbagbogbo pe, Gbigbega li Oluwa.

Ka pipe ipin O. Daf 40

Wo O. Daf 40:16 ni o tọ