Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 40:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi kò fi ododo rẹ sin li aiya mi, emi o sọ̀rọ otitọ ati igbala rẹ: emi kò si pa iṣeun-ifẹ rẹ ati otitọ rẹ mọ́ kuro lọdọ ijọ nla nì.

Ka pipe ipin O. Daf 40

Wo O. Daf 40:10 ni o tọ