Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 38:20-22 Yorùbá Bibeli (YCE)

20. Awọn ti o si nfi buburu san rere li ọta mi; nitori emi ntọpa ohun ti iṣe rere.

21. Oluwa, máṣe kọ̀ mi silẹ; Ọlọrun mi, máṣe jina si mi.

22. Yara lati ran mi lọwọ, Oluwa igbala mi.

Ka pipe ipin O. Daf 38