Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 27:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ohun kan li emi ntọrọ li ọdọ Oluwa, on na li emi o ma wakiri: ki emi ki o le ma gbe inu ile Oluwa li ọjọ aiye mi gbogbo, ki emi ki o le ma wò ẹwà Oluwa, ki emi ki o si ma fi inu-didùn wò tempili rẹ̀.

Ka pipe ipin O. Daf 27

Wo O. Daf 27:4 ni o tọ