Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 26:11-12 Yorùbá Bibeli (YCE)

11. Ṣugbọn bi o ṣe ti emi, emi o ma rìn ninu ìwatitọ mi: rà mi pada, ki o si ṣãnu fun mi.

12. Ẹsẹ mi duro ni ibi titẹju: ninu awọn ijọ li emi o ma fi ibukún fun Oluwa.

Ka pipe ipin O. Daf 26