Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 19:3-5 Yorùbá Bibeli (YCE)

3. Kò si ohùn kan tabi ède kan, nibiti a kò gbọ́ iró wọn.

4. Iró wọn la gbogbo aiye ja, ati ọ̀rọ wọn de opin aiye: ninu wọn li o gbe pagọ fun õrun.

5. Ti o dabi ọkọ iyawo ti njade ti iyẹwu rẹ̀ wá, ti o si yọ̀ bi ọkunrin alagbara lati sure ije.

Ka pipe ipin O. Daf 19