Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 17:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Fi iṣeun ifẹ iyanu rẹ hàn, iwọ ti o fi ọwọ ọtún rẹ gbà awọn ti o gbẹkẹle ọ là, lọwọ awọn ti o dide si wọn.

Ka pipe ipin O. Daf 17

Wo O. Daf 17:7 ni o tọ