Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 148:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si gbé iwo kan soke fun awọn enia rẹ̀, iyìn fun gbogbo enia mimọ́ rẹ̀; ani awọn ọmọ Israeli, awọn enia ti o sunmọ ọdọ rẹ̀. Ẹ fi iyìn fun Oluwa.

Ka pipe ipin O. Daf 148

Wo O. Daf 148:14 ni o tọ