Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 14:6-7 Yorùbá Bibeli (YCE)

6. Ẹnyin dojutì ìmọ awọn talaka, ṣugbọn Oluwa li àbo rẹ̀.

7. Tani yio fi igbala fun Israeli lati Sioni jade wá! nigbati Oluwa ba mu ikólọ awọn enia rẹ̀ pada bọ̀, Jakobu yio yọ̀, inu Israeli yio si dùn.

Ka pipe ipin O. Daf 14