Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 123:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kiyesi i, bi oju awọn iranṣẹkunrin ti ima wò ọwọ awọn baba wọn, ati bi oju iranṣẹ-birin ti ima wò ọwọ iya rẹ̀; bẹ̃li oju wa nwò Oluwa Ọlọrun wa, titi yio fi ṣãnu fun wa.

Ka pipe ipin O. Daf 123

Wo O. Daf 123:2 ni o tọ