Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 114:1-5 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. NIGBATI Israeli jade kuro ni Egipti, ti ara-ile Jakobu kuro ninu àjeji ède enia;

2. Juda di ibi mimọ́ rẹ̀, Israeli di ijọba rẹ̀.

3. Okun ri i, o si sá: Jordani pada sẹhin.

4. Awọn òke nla nfò bi àgbo, ati awọn òke kekèke bi ọdọ-agutan.

5. Kili o ṣe ọ, iwọ okun, ti iwọ fi sá? iwọ Jordani ti iwọ fi pada sẹhin?

Ka pipe ipin O. Daf 114