Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 110:5-7 Yorùbá Bibeli (YCE)

5. Oluwa li ọwọ ọtún rẹ ni yio lù awọn ọba jalẹ li ọjọ ibinu rẹ̀.

6. Yio ṣe idajọ lãrin awọn keferi, yio fi okú kún ibi wọnni; yio fọ́ ori lori ilẹ pupọ̀.

7. Yio ma mu ninu odò na li ọ̀na: nitorina ni yio ṣe gbé ori soke.

Ka pipe ipin O. Daf 110