Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 109:24-26 Yorùbá Bibeli (YCE)

24. Ẽkun mi di ailera nitori igbawẹ; ẹran-ara mi si gbẹ nitori ailọra.

25. Emi di ẹ̀gan fun wọn pẹlu: nigbati nwọn wò mi, nwọn mi ori wọn.

26. Ràn mi lọwọ, Oluwa Ọlọrun mi: gbà mi gẹgẹ bi ãnu rẹ.

Ka pipe ipin O. Daf 109