Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 108:11-13 Yorùbá Bibeli (YCE)

11. Iwọ Ọlọrun ha kọ́, ẹniti o ti ṣa wa tì? Ọlọrun, iwọ kì yio si ba awọn ogun wa jade lọ?

12. Fun wa ni iranlọwọ ninu ipọnju: nitori asan ni iranlọwọ enia.

13. Nipasẹ Ọlọrun li awa o ṣe akin; nitori on ni yio tẹ̀ awọn ọta wa mọlẹ.

Ka pipe ipin O. Daf 108