Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 108:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. OLỌRUN, ọkàn mi ti mura, emi o ma kọrin, emi o si ma fi ogo mi kọrin iyìn.

2. Ji, ohun-elo orin mimọ́ ati dùrù: emi tikarami yio si ji ni kutukutu.

3. Emi o ma yìn ọ, Oluwa, ninu awọn enia: emi o mã kọrin si ọ ninu awọn orilẹ-ède.

Ka pipe ipin O. Daf 108