Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 106:25-27 Yorùbá Bibeli (YCE)

25. Ṣugbọn nwọn nkùn ninu agọ wọn, nwọn kò si feti si ohùn Oluwa.

26. Nitorina li o ṣe gbé ọwọ rẹ̀ soke si wọn, lati bì wọn ṣubu li aginju:

27. Lati bì iru-ọmọ wọn ṣubu pẹlu lãrin awọn orilẹ-ède, ati lati fún wọn ka kiri ni ilẹ wọnni.

Ka pipe ipin O. Daf 106