Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 104:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jẹ ki awọn ẹlẹṣẹ ki o run kuro li aiye, ki awọn enia buburu ki o má si mọ. Fi ibukún fun Oluwa, iwọ ọkàn mi. Ẹ fi iyìn fun Oluwa.

Ka pipe ipin O. Daf 104

Wo O. Daf 104:35 ni o tọ