Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

O. Daf 101:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lojojumọ li emi o ma run gbogbo enia buburu ilẹ na; ki emi ki o le ke gbogbo oluṣe buburu kuro ni ilu Oluwa.

Ka pipe ipin O. Daf 101

Wo O. Daf 101:8 ni o tọ