Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 9:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi alejò kan ba si nṣe atipo lọdọ nyin, ti o si nfẹ́ pa irekọja mọ́ fun OLUWA; gẹgẹ bi ìlana irekọja, ati gẹgẹ bi aṣẹ rẹ̀, ni ki o ṣe bẹ̃: ìlana kan ni ki ẹnyin ki o ní, ati fun alejò, ati fun ibilẹ.

Ka pipe ipin Num 9

Wo Num 9:14 ni o tọ