Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 8:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyi ni ti awọn ọmọ Lefi: lati ẹni ọdún mẹdọgbọ̀n lọ ati jù bẹ̃ lọ ni ki nwọn ki o ma wọle lọ lati ṣe iṣẹ-ìsin ninu agọ́ ajọ.

Ka pipe ipin Num 8

Wo Num 8:24 ni o tọ