Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 8:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoripe ti emi ni gbogbo akọ́bi ninu awọn ọmọ Israeli, ati ti enia ati ti ẹran: li ọjọ́ ti mo kọlù gbogbo akọ̀bi ni ilẹ Egipti ni mo ti yà wọn simimọ́ fun ara mi.

Ka pipe ipin Num 8

Wo Num 8:17 ni o tọ