Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 8:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki awọn ọmọ Lefi ki o si fi ọwọ́ wọn lé ori ẹgbọrọ akọmalu wọnni: ki iwọ ki o si ru ọkan li ẹbọ ẹ̀ṣẹ, ati ekeji li ẹbọ sisun si OLUWA, lati ṣètutu fun awọn ọmọ Lefi.

Ka pipe ipin Num 8

Wo Num 8:12 ni o tọ