Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 6:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o yà ara rẹ̀ kuro ninu ọti-waini tabi ọti lile; ki o má si ṣe mu ọti-waini kikan, tabi ọti lile ti o kan, ki o má si ṣe mu ọti eso-àjara kan, bẹ̃ni kò gbọdọ jẹ eso-àjara tutù tabi gbigbẹ.

Ka pipe ipin Num 6

Wo Num 6:3 ni o tọ